mediawiki-extensions-AbuseF.../i18n/yo.json

83 lines
5.5 KiB
JSON
Raw Normal View History

{
"@metadata": {
"authors": [
"Demmy",
"Fitoschido",
"SolutionTomi",
"Wikicology"
]
},
"abusefilter-disallowed": "Ìgbéṣe yìí ti jẹ́ dídámọ̀ fúnrararẹ̀ bíi eléwu, bíi bẹ́ẹ̀ ó ti jẹ́ dídílọ́nà.\nTí ẹ bá nígbàgbọ́ pé àtúnṣe yín jẹ́ awúlò, ẹ jọ̀wọ́ ẹ fi tó olùmójútó kan létí ohun tí ẹ fẹ́ ṣe.\nÌjúwe ní sókí òfin ìbàjẹ́ tí ó bá ìgbéṣe yín mu ni: $1",
"abusefilter-blocked-display": "Ìgbéṣe yìí ti jẹ́ dídámọ̀ fúnrararẹ̀ bíi eléwu, bíi bẹ́ẹ̀ ẹ ti jẹ́ dídílọ́nà láti ṣeé.\nBákannáà láti dá àbò bo {{SITENAME}}, àpamọ́ oníṣe yín àti gbogbo àwọn àdírẹ́sì IP tí wọ́n jọṣe mọ́ọn ti jẹ́ dídílọ́nà láti ṣàtúnṣe.\nTó bá jẹ́ pé àsìṣe ló ṣẹlẹ̀, ẹ jọ̀wọ́ ẹ fi tó olùmójútó kan létí.\nÌjúwe ní sókí òfin ìbàjẹ́ tí ó bá ìgbéṣe yín mu ni: $1",
"action-abusefilter-protected-vars-log": "Wo àwọn àkọ́lẹ̀ tí ó ṣàfihàn nǹkan onírúurú ti a fi pamọ́",
"abusefilter-log-search-user": "Oníṣe:",
"abusefilter-log-search-filter": "Nọ́mbà Ìdámọ̀ Ajọ̀:",
"abusefilter-log-search-title": "Àkọlé:",
"abusefilter-log-search-wiki": "Wiki:",
"abusefilter-log-search-submit": "Àwárí",
"abusefilter-log-noactions": "kankan",
"abusefilter-log-details-diff": "Àwọn ìyípadà nínú àtúnṣe",
"abusefilter-log-hide-reason": "Ìdíẹ̀:",
"abusefilter-list-limit": "Iye lójúewé kọ̀ọ̀kan",
"abusefilter-hidden": "Àdáni",
"abusefilter-enabled": "Gbígbàláyè",
"abusefilter-deleted": "Píparẹ́",
"abusefilter-disabled": "Dídálẹ́kun",
"abusefilter-tools-reautoconfirm-user": "Oníṣe:",
"abusefilter-edit-status-label": "Àwọn statistiki:",
"abusefilter-edit-deleted": "Fàlàsí bíi píparẹ́",
"abusefilter-edit-lastmod-text": "$1 latọwọ́ $2",
"abusefilter-throttle-page": "ojú ewé",
"abusefilter-edit-warn-other": "Ìránṣẹ́ míràn",
"abusefilter-edit-warn-actions": "Àwọn ìgbéṣe:",
"abusefilter-edit-warn-preview": "Àkọ́yẹ̀wò ìránṣẹ́ ṣíṣàyàn",
"abusefilter-edit-warn-edit": "Ìdá/Àtúnṣe ìránṣẹ́ ṣíṣàyàn",
"abusefilter-edit-history": "Ìtàn:",
"abusefilter-edit-tools": "Àwọn irinṣẹ́:",
"abusefilter-edit-builder-group-op-arithmetic": "Àwọn amúṣeṣẹ́ ìsirò",
"abusefilter-edit-builder-op-arithmetic-addition": "Ìròpọ̀ (+)",
"abusefilter-edit-builder-op-arithmetic-subtraction": "Ìyọkúrò (-)",
"abusefilter-edit-builder-op-arithmetic-multiplication": "Ìsọdipúpọ̀ (*)",
"abusefilter-edit-builder-op-arithmetic-divide": "Pínpín (/)",
"abusefilter-edit-builder-op-arithmetic-modulo": "Ìṣẹ́kù (%)",
"abusefilter-edit-builder-op-arithmetic-pow": "Agbára (**)",
"abusefilter-edit-builder-group-op-comparison": "Àwọn amúṣeṣẹ́ ìfiwéra",
"abusefilter-edit-builder-op-comparison-equal": "Iye dọ́gba mọ́ (==)",
"abusefilter-edit-builder-op-comparison-notequal": "Iye kò dọ́gba mọ́ (!=)",
"abusefilter-edit-builder-op-comparison-lt": "Dínjùlọ sí (<)",
"abusefilter-edit-builder-op-comparison-gt": "Pọ̀jùlọ sí (>)",
"abusefilter-edit-builder-op-comparison-lte": "Kéré jùlọ tàbí dọ́gba mọ́ (<=)",
"abusefilter-edit-builder-op-comparison-gte": "Tóbi jùlọ tàbí dọ́gba mọ́ (>=)",
"abusefilter-edit-builder-group-op-bool": "Àwọn amúṣeṣẹ́ Boole",
"abusefilter-edit-builder-op-bool-not": "Kòjẹ́ (!)",
"abusefilter-edit-builder-op-bool-and": "Àti (&)",
"abusefilter-edit-builder-op-bool-or": "Tàbí (|)",
"abusefilter-edit-builder-group-funcs": "Àwọn ìgbéṣe",
"abusefilter-edit-builder-vars-accountname": "Orúkọ ìforúkọpamọ́ (nígbà ìdá ìforúkọpamọ́)",
"abusefilter-edit-builder-vars-action": "Ìgbéṣe",
"abusefilter-edit-builder-vars-newsize": "Ìtóbi ojúewé tuntun",
"abusefilter-edit-builder-vars-removedlines": "Àwọn ìlà tó jẹ́ yíyọkúrò nínú àtúnṣe",
"abusefilter-edit-builder-vars-page-id": "Nọ́mbà Ìdámọ̀ Ojúewé",
"abusefilter-history-foruser": "Àwọn ìyípadà látọwọ́ $1",
"abusefilter-history-hidden": "Bíbòmọ́lẹ̀",
"abusefilter-history-enabled": "Gbígbàláyè",
"abusefilter-history-timestamp": "Àsìkò",
"abusefilter-history-user": "Oníṣe",
"abusefilter-history-deleted": "Píparẹ́",
"abusefilter-history-filterid": "Ajọ̀",
"abusefilter-history-select-user": "Oníṣe:",
"abusefilter-history-diff": "Àwọn àtúnṣe",
"abusefilter-action-tag": "Ṣàlẹ̀mọ́",
"abusefilter-action-warn": "Ṣèkìlọ̀",
"abusefilter-action-block": "Dílọ́nà",
"abusefilter-test-user": "Àwọn ìyípadà látọwọ́ oníṣe:",
"abusefilter-test-period-start": "Àwọn ìyípadà tó ṣẹlẹ̀ lẹ́yìn:",
"abusefilter-test-period-end": "Àwọn ìyípadà tó ṣẹlẹ̀ síwájú:",
"abusefilter-test-page": "Àwọn ìyípadà tó ṣẹlẹ̀ sí ojúewé:",
"abusefilter-changeslist-examine": "ṣàgbéwò",
"abusefilter-examine-legend": "Àṣàyàn àwọn ìyípadà",
"abusefilter-examine-submit": "Ṣàwárí",
"abusefilter-protected-vars-log-header": "Èyí ni àkọ́lẹ̀ ti:\n\n# wíwò nǹkan onírúurú ti a fi pamọ́\n\n# ṣíṣe àyípadà sí ìpele ìbáwolé fún àwọn olùṣàmúlò fún wíwò nǹkan onírúurú ti a fi pamọ́",
"log-action-filter-abusefilter-protected-vars": "Irú iṣẹ́ àgbéṣe"
}